From the recording The Journey
Lyrics
Mummy mi nílé e, Bàbá mi la jọ
Màmá mi pray for me, ká má ṣ'àgbákò
Gbogbo ibi tá a bá ń dé, ká má r'àtakò
Àfi Ọlọ́run, kò sí ẹ̀yàn kan, kò s'alábàárò
Mummy mi nílé e, Bàbá mi la jọ
Màmá mi pray for me, ká má ṣ'àgbákò
Gbogbo ibi tá a bá ń dé, ká má r'àtakò
Àfi Ọlọ́run, kò sí ẹ̀yàn kan, kò s'alábàárò
Kọ́ má fi wa parọ ibi fi wa parọ kọ
I no forget wetin you tell me, say make I no fold
Mo mọ̀ pé ó máa set l'ọkàn mi, pé òsì má tó o o (ahh ahh)
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò ó
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò ó ò (ahh)
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò ó ò
Na church we left, we no leave God
Grinding on the street, we no give up
Nobody go tell you make you serious
Poverty and hunger dey there
Oga má lọ lẹ́lẹ́
Ó j'owó jájọ dé bẹ́ẹ̀
I gat family to take care (ahh)
Mo lè gbé gẹ́ẹ̀ sí (ahh ahh)
Mo lè gbé gẹ́ẹ̀ sí
Mummy mi nílé e
(You say?)
Mummy mi nílé e, Bàbá mi la jọ
Màmá mi pray for me, ká má ṣ'àgbákò
Gbogbo ibi tá a bá ń dé, ká má r'àtakò
Àfi Ọlọ́run, kò sí ẹ̀yàn kan, kò s'alábàárò
Kọ́ má fi wa parọ ibi fi wa parọ kọ
I no forget wetin you tell me, say make I no fold
Mo mọ̀ pé ó máa set l'ọkàn mi, pé òsì má tó o o
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò ó
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò o oh (ahh)
Nípa ìfẹ́ Olùgbàlà
Àwa ò ní fò
Àwa ò ní fò ó ò

